-
1 Jòhánù 4:2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 Báyìí lẹ ṣe máa mọ̀ bóyá ọ̀dọ̀ Ọlọ́run ni ọ̀rọ̀ kan tó ní ìmísí ti wá: Gbogbo ọ̀rọ̀ onímìísí tó bá fi hàn pé Jésù Kristi wá nínú ẹran ara jẹ́ látọ̀dọ̀ Ọlọ́run.+
-