Hébérù 3:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Torí àfi tí a bá ní irú ìdánilójú tí a ní níbẹ̀rẹ̀ títí dé òpin, la máa fi lè ní ìpín pẹ̀lú Kristi.*+ 1 Jòhánù 2:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Ẹnikẹ́ni tó bá sẹ́ Ọmọ kò ní Baba.+ Ẹnikẹ́ni tó bá sọ pé òun mọ Ọmọ+ ní Baba pẹ̀lú.+
14 Torí àfi tí a bá ní irú ìdánilójú tí a ní níbẹ̀rẹ̀ títí dé òpin, la máa fi lè ní ìpín pẹ̀lú Kristi.*+