2 Jòhánù 4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Inú mi dùn gan-an torí mo rí lára àwọn ọmọ rẹ tó ń rìn nínú òtítọ́,+ bí Baba ṣe pa á láṣẹ fún wa.