1 Jòhánù 3:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Gbogbo ẹni tí a bí látọ̀dọ̀ Ọlọ́run kì í sọ ẹ̀ṣẹ̀ dàṣà,+ torí irúgbìn* Rẹ̀ wà nínú ẹni náà, kò sì lè sọ ẹ̀ṣẹ̀ dàṣà, torí ọ̀dọ̀ Ọlọ́run la ti bí i.+
9 Gbogbo ẹni tí a bí látọ̀dọ̀ Ọlọ́run kì í sọ ẹ̀ṣẹ̀ dàṣà,+ torí irúgbìn* Rẹ̀ wà nínú ẹni náà, kò sì lè sọ ẹ̀ṣẹ̀ dàṣà, torí ọ̀dọ̀ Ọlọ́run la ti bí i.+