-
1 Tímótì 6:12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
12 Ja ìjà rere ti ìgbàgbọ́; di ìyè àìnípẹ̀kun mú gírígírí, èyí tí a torí rẹ̀ pè ọ́, tí o sì wàásù rẹ̀ dáadáa ní gbangba lójú ọ̀pọ̀ ẹlẹ́rìí.
-