Mátíù 5:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 “Aláyọ̀ ni àwọn aláàánú,+ torí a máa ṣàánú wọn. Mátíù 9:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Torí náà, ẹ lọ kọ́ ohun tí ọ̀rọ̀ yìí túmọ̀ sí: ‘Àánú ni mo fẹ́, kì í ṣe ẹbọ.’+ Torí kì í ṣe àwọn olódodo ni mo wá pè, àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀ ni.” Jémíìsì 2:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Torí ẹni tí kì í ṣàánú kò ní rí àánú gbà nígbà ìdájọ́.+ Àánú máa ń borí ìdájọ́.
13 Torí náà, ẹ lọ kọ́ ohun tí ọ̀rọ̀ yìí túmọ̀ sí: ‘Àánú ni mo fẹ́, kì í ṣe ẹbọ.’+ Torí kì í ṣe àwọn olódodo ni mo wá pè, àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀ ni.”