Jémíìsì 1:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Àmọ́ kó máa fi ìgbàgbọ́ béèrè,+ kó má ṣiyèméjì rárá,+ torí ẹni tó ń ṣiyèméjì dà bí ìgbì òkun tí atẹ́gùn ń fẹ́ káàkiri.
6 Àmọ́ kó máa fi ìgbàgbọ́ béèrè,+ kó má ṣiyèméjì rárá,+ torí ẹni tó ń ṣiyèméjì dà bí ìgbì òkun tí atẹ́gùn ń fẹ́ káàkiri.