1 Kọ́ríńtì 16:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 nítorí ilẹ̀kùn ńlá ti ṣí sílẹ̀ fún mi láti ṣe iṣẹ́ púpọ̀,+ àmọ́ ọ̀pọ̀ alátakò ló wà. 2 Kọ́ríńtì 2:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Nígbà tí mo dé Tíróásì+ láti kéde ìhìn rere nípa Kristi, tí ilẹ̀kùn kan sì ṣí fún mi nínú Olúwa,