ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Lúùkù 8:15
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 Ní ti èyí tó wà lórí iyẹ̀pẹ̀ tó dáa, àwọn yìí ló jẹ́ pé, lẹ́yìn tí wọ́n fi ọkàn tó tọ́, tó sì dáa gbọ́ ọ̀rọ̀ náà,+ wọ́n fi sọ́kàn, wọ́n sì ń fi ìfaradà so èso.+

  • Lúùkù 21:19
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 19 Tí ẹ bá ní ìfaradà, ẹ máa lè pa ẹ̀mí yín mọ́.*+

  • 2 Tímótì 2:12
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 12 tí a bá ń fara dà á nìṣó, a tún jọ máa jọba;+ tí a bá sẹ́ ẹ, òun náà máa sẹ́ wa;+

  • Hébérù 10:36
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 36 Nítorí ẹ nílò ìfaradà,+ pé lẹ́yìn tí ẹ ti ṣe ìfẹ́ Ọlọ́run, kí ẹ lè rí ohun tí ó ṣèlérí náà gbà.

  • Hébérù 12:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 Ní tòótọ́, ẹ fara balẹ̀ ronú nípa ẹni tó fara da irú ọ̀rọ̀ kòbákùngbé bẹ́ẹ̀ láti ẹnu àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀,+ tí wọ́n ń ṣàkóbá fún ara wọn, kó má bàa rẹ̀ yín, kí ẹ má sì sọ̀rètí nù.*+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́