Hébérù 12:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Àmọ́ ẹ ti sún mọ́ Òkè Síónì+ àti ìlú Ọlọ́run alààyè, Jerúsálẹ́mù ti ọ̀run+ àti ọ̀kẹ́ àìmọye* àwọn áńgẹ́lì Ìfihàn 21:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Bákan náà mo rí ìlú mímọ́ náà, Jerúsálẹ́mù Tuntun, ó ń ti ọ̀run sọ̀ kalẹ̀ látọ̀dọ̀ Ọlọ́run,+ bí ìyàwó tí a ṣe lọ́ṣọ̀ọ́ fún ọkọ rẹ̀.+
22 Àmọ́ ẹ ti sún mọ́ Òkè Síónì+ àti ìlú Ọlọ́run alààyè, Jerúsálẹ́mù ti ọ̀run+ àti ọ̀kẹ́ àìmọye* àwọn áńgẹ́lì
2 Bákan náà mo rí ìlú mímọ́ náà, Jerúsálẹ́mù Tuntun, ó ń ti ọ̀run sọ̀ kalẹ̀ látọ̀dọ̀ Ọlọ́run,+ bí ìyàwó tí a ṣe lọ́ṣọ̀ọ́ fún ọkọ rẹ̀.+