Òwe 8:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Jèhófà ṣẹ̀dá mi gẹ́gẹ́ bí ìbẹ̀rẹ̀ ọ̀nà rẹ̀,+Àkọ́bẹ̀rẹ̀ àwọn àṣeyọrí rẹ̀ ti ìgbà láéláé.+ Kólósè 1:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Òun ni àwòrán Ọlọ́run tí a kò lè rí,+ àkọ́bí nínú gbogbo ẹ̀dá; +