Mátíù 26:64 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 64 Jésù sọ fún un pé: “Ìwọ fúnra rẹ ti sọ ọ́. Àmọ́ mò ń sọ fún yín pé: Láti ìsinsìnyí lọ, ẹ máa rí Ọmọ èèyàn+ tó jókòó ní ọwọ́ ọ̀tún agbára,+ tó sì ń bọ̀ lórí àwọn àwọsánmà* ojú ọ̀run.”+ Máàkù 13:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Nígbà náà, wọ́n máa wá rí Ọmọ èèyàn+ tó ń bọ̀ nínú àwọsánmà* pẹ̀lú agbára àti ògo ńlá.+
64 Jésù sọ fún un pé: “Ìwọ fúnra rẹ ti sọ ọ́. Àmọ́ mò ń sọ fún yín pé: Láti ìsinsìnyí lọ, ẹ máa rí Ọmọ èèyàn+ tó jókòó ní ọwọ́ ọ̀tún agbára,+ tó sì ń bọ̀ lórí àwọn àwọsánmà* ojú ọ̀run.”+