Ìfihàn 4:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ẹ̀dá alààyè àkọ́kọ́ dà bíi kìnnìún,+ ẹ̀dá alààyè kejì dà bí akọ ọmọ màlúù,+ ẹ̀dá alààyè kẹta+ ní ojú bíi ti èèyàn, ẹ̀dá alààyè kẹrin+ sì dà bí ẹyẹ idì tó ń fò.+
7 Ẹ̀dá alààyè àkọ́kọ́ dà bíi kìnnìún,+ ẹ̀dá alààyè kejì dà bí akọ ọmọ màlúù,+ ẹ̀dá alààyè kẹta+ ní ojú bíi ti èèyàn, ẹ̀dá alààyè kẹrin+ sì dà bí ẹyẹ idì tó ń fò.+