Mátíù 10:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Gbogbo èèyàn sì máa kórìíra yín nítorí orúkọ mi,+ ṣùgbọ́n ẹni tó bá fara dà á* dé òpin máa rí ìgbàlà.+ 2 Tímótì 2:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 tí a bá ń fara dà á nìṣó, a tún jọ máa jọba;+ tí a bá sẹ́ ẹ, òun náà máa sẹ́ wa;+
22 Gbogbo èèyàn sì máa kórìíra yín nítorí orúkọ mi,+ ṣùgbọ́n ẹni tó bá fara dà á* dé òpin máa rí ìgbàlà.+