-
Àìsáyà 34:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 Gbogbo ọmọ ogun ọ̀run máa jẹrà dà nù,
A sì máa ká ọ̀run jọ bí àkájọ ìwé.
Gbogbo ọmọ ogun wọn máa rọ dà nù,
Bí ewé tó ti rọ ṣe ń já bọ́ lára àjàrà
Àti bí èso ọ̀pọ̀tọ́ tó ti bà jẹ́ ṣe ń já bọ́ lára igi ọ̀pọ̀tọ́.
-