Sáàmù 15:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Jèhófà, ta ló lè jẹ́ àlejò nínú àgọ́ rẹ? Ta ló lè máa gbé ní òkè mímọ́ rẹ?+ Ìfihàn 21:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ni mo bá gbọ́ ohùn kan tó dún ketekete látorí ìtẹ́ náà, ó sọ pé: “Wò ó! Àgọ́ Ọlọ́run wà pẹ̀lú aráyé, á máa bá wọn gbé, wọ́n á sì jẹ́ èèyàn rẹ̀. Ọlọ́run fúnra rẹ̀ máa wà pẹ̀lú wọn.+
3 Ni mo bá gbọ́ ohùn kan tó dún ketekete látorí ìtẹ́ náà, ó sọ pé: “Wò ó! Àgọ́ Ọlọ́run wà pẹ̀lú aráyé, á máa bá wọn gbé, wọ́n á sì jẹ́ èèyàn rẹ̀. Ọlọ́run fúnra rẹ̀ máa wà pẹ̀lú wọn.+