Jòhánù 10:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Èmi ni olùṣọ́ àgùntàn àtàtà;+ olùṣọ́ àgùntàn àtàtà máa ń fi ẹ̀mí* rẹ̀ lélẹ̀ nítorí àwọn àgùntàn.+