Ìfihàn 2:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 “Bákan náà, kọ̀wé sí áńgẹ́lì ìjọ ní Símínà pé: Àwọn nǹkan tí ‘Ẹni Àkọ́kọ́ àti Ẹni Ìkẹyìn’+ sọ nìyí, ẹni tó kú tẹ́lẹ̀, tó sì pa dà wà láàyè:+
8 “Bákan náà, kọ̀wé sí áńgẹ́lì ìjọ ní Símínà pé: Àwọn nǹkan tí ‘Ẹni Àkọ́kọ́ àti Ẹni Ìkẹyìn’+ sọ nìyí, ẹni tó kú tẹ́lẹ̀, tó sì pa dà wà láàyè:+