Ìfihàn 9:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Áńgẹ́lì kẹfà+ fun kàkàkí rẹ̀.+ Mo sì gbọ́ ohùn kan, ó wá látinú àwọn ìwo tó wà lórí pẹpẹ, èyí tí wọ́n fi wúrà ṣe+ tó wà níwájú Ọlọ́run,
13 Áńgẹ́lì kẹfà+ fun kàkàkí rẹ̀.+ Mo sì gbọ́ ohùn kan, ó wá látinú àwọn ìwo tó wà lórí pẹpẹ, èyí tí wọ́n fi wúrà ṣe+ tó wà níwájú Ọlọ́run,