Ìfihàn 9:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Ìyọnu àkọ́kọ́ ti kọjá. Wò ó! Ìyọnu méjì míì+ ń bọ̀ lẹ́yìn àwọn nǹkan yìí. Ìfihàn 11:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Ìyọnu kejì+ ti kọjá. Wò ó! Ìyọnu kẹta ń bọ̀ kíákíá.