Jóẹ́lì 2:4, 5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Wọ́n rí bí ẹṣin,Wọ́n sì ń sáré bí ẹṣin ogun.+ 5 Ìró wọn dà bíi ti àwọn kẹ̀kẹ́ ẹṣin tó ń bẹ́ gìjà lórí àwọn òkè,+Bí ìró iná ajófòfò tó ń jó àgékù pòròpórò. Wọ́n dà bí àwọn alágbára, tí wọ́n tò lọ́wọ̀ọ̀wọ́ láti jagun.+
4 Wọ́n rí bí ẹṣin,Wọ́n sì ń sáré bí ẹṣin ogun.+ 5 Ìró wọn dà bíi ti àwọn kẹ̀kẹ́ ẹṣin tó ń bẹ́ gìjà lórí àwọn òkè,+Bí ìró iná ajófòfò tó ń jó àgékù pòròpórò. Wọ́n dà bí àwọn alágbára, tí wọ́n tò lọ́wọ̀ọ̀wọ́ láti jagun.+