Ìfihàn 9:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 A ò gbà kí àwọn eéṣú náà pa wọ́n, àmọ́ kí wọ́n dá wọn lóró fún oṣù márùn-ún, oró wọn sì dà bí ìgbà tí àkekèé+ bá ta èèyàn.
5 A ò gbà kí àwọn eéṣú náà pa wọ́n, àmọ́ kí wọ́n dá wọn lóró fún oṣù márùn-ún, oró wọn sì dà bí ìgbà tí àkekèé+ bá ta èèyàn.