ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́kísódù 19:16
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 16 Ní àárọ̀ ọjọ́ kẹta, ààrá sán, mànàmáná kọ. Àwọsánmà ṣú+ bo orí òkè, ìró ìwo sì dún sókè gan-an, ẹ̀rù wá ń ba gbogbo àwọn tó wà nínú àgọ́.+

  • Ìfihàn 4:5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 5 Mànàmáná+ àti ohùn àti ààrá+ sì ń jáde wá láti ibi ìtẹ́ náà; fìtílà méje tó ní iná ń jó níwájú ìtẹ́ náà, àwọn yìí sì túmọ̀ sí ẹ̀mí méje ti Ọlọ́run.+

  • Ìfihàn 11:19
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 19 A ṣí ibi mímọ́ tẹ́ńpìlì Ọlọ́run ní ọ̀run, a sì rí àpótí májẹ̀mú rẹ̀ nínú ibi mímọ́ tẹ́ńpìlì rẹ̀.+ Mànàmáná kọ yẹ̀rì, a sì gbọ́ ohùn, ààrá sán, ìmìtìtì ilẹ̀ wáyé, òjò yìnyín rẹpẹtẹ sì rọ̀.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́