Máàkù 4:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Ó sọ fún wọn pé: “Ẹ̀yin la jẹ́ kó mọ àṣírí mímọ́+ Ìjọba Ọlọ́run, àmọ́ àpèjúwe ni gbogbo nǹkan jẹ́ fún àwọn tó wà ní òde,+
11 Ó sọ fún wọn pé: “Ẹ̀yin la jẹ́ kó mọ àṣírí mímọ́+ Ìjọba Ọlọ́run, àmọ́ àpèjúwe ni gbogbo nǹkan jẹ́ fún àwọn tó wà ní òde,+