Ìfihàn 13:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ó fún un ní ẹnu tó ń sọ àwọn nǹkan ńláńlá àti ọ̀rọ̀ òdì, ó sì fún un ní àṣẹ tó máa lò fún oṣù méjìlélógójì (42).+
5 Ó fún un ní ẹnu tó ń sọ àwọn nǹkan ńláńlá àti ọ̀rọ̀ òdì, ó sì fún un ní àṣẹ tó máa lò fún oṣù méjìlélógójì (42).+