-
Sekaráyà 4:12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
12 Mo tún bi í lẹ́ẹ̀kejì pé: “Kí ni ìdì méjì ẹ̀ka* igi ólífì náà túmọ̀ sí, tó ní òpó wúrà méjì tí òróró wúrà ń ṣàn jáde láti inú rẹ̀?”
-