Ìfihàn 12:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Dírágónì náà wá bínú gidigidi sí obìnrin náà, ó sì lọ bá àwọn tó ṣẹ́ kù lára ọmọ* rẹ̀ jagun,+ àwọn tó ń pa àṣẹ Ọlọ́run mọ́, tí iṣẹ́ wọn sì jẹ́ láti jẹ́rìí Jésù.+ Ìfihàn 13:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 A gbà á láyè láti bá àwọn ẹni mímọ́ jagun kó sì ṣẹ́gun wọn,+ a sì fún un ní àṣẹ lórí gbogbo ẹ̀yà, èèyàn, ahọ́n* àti orílẹ̀-èdè.
17 Dírágónì náà wá bínú gidigidi sí obìnrin náà, ó sì lọ bá àwọn tó ṣẹ́ kù lára ọmọ* rẹ̀ jagun,+ àwọn tó ń pa àṣẹ Ọlọ́run mọ́, tí iṣẹ́ wọn sì jẹ́ láti jẹ́rìí Jésù.+
7 A gbà á láyè láti bá àwọn ẹni mímọ́ jagun kó sì ṣẹ́gun wọn,+ a sì fún un ní àṣẹ lórí gbogbo ẹ̀yà, èèyàn, ahọ́n* àti orílẹ̀-èdè.