1 Jòhánù 2:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Mo kọ̀wé sí ẹ̀yin bàbá, torí ẹ ti wá mọ ẹni tó wà láti ìbẹ̀rẹ̀. Mo kọ̀wé sí ẹ̀yin ọ̀dọ́kùnrin, torí ẹ jẹ́ alágbára,+ ọ̀rọ̀ Ọlọ́run wà nínú yín,+ ẹ sì ti ṣẹ́gun ẹni burúkú náà.+
14 Mo kọ̀wé sí ẹ̀yin bàbá, torí ẹ ti wá mọ ẹni tó wà láti ìbẹ̀rẹ̀. Mo kọ̀wé sí ẹ̀yin ọ̀dọ́kùnrin, torí ẹ jẹ́ alágbára,+ ọ̀rọ̀ Ọlọ́run wà nínú yín,+ ẹ sì ti ṣẹ́gun ẹni burúkú náà.+