Ìfihàn 13:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Ó ń ṣi àwọn tó ń gbé ayé lọ́nà, torí àwọn iṣẹ́ àmì tí a gbà á láyè láti ṣe lójú ẹranko náà, bó ṣe ń sọ fún àwọn tó ń gbé ayé pé kí wọ́n ṣe ère+ ẹranko tó ní ọgbẹ́ idà, síbẹ̀ tó sọjí.+
14 Ó ń ṣi àwọn tó ń gbé ayé lọ́nà, torí àwọn iṣẹ́ àmì tí a gbà á láyè láti ṣe lójú ẹranko náà, bó ṣe ń sọ fún àwọn tó ń gbé ayé pé kí wọ́n ṣe ère+ ẹranko tó ní ọgbẹ́ idà, síbẹ̀ tó sọjí.+