Dáníẹ́lì 3:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ọba Nebukadinésárì ṣe ère wúrà kan, gíga rẹ̀ jẹ́ ọgọ́ta (60) ìgbọ̀nwọ́,* fífẹ̀ rẹ̀ sì jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ mẹ́fà.* Ó gbé e kalẹ̀ sí pẹ̀tẹ́lẹ̀ Dúrà ní ìpínlẹ̀* Bábílónì.
3 Ọba Nebukadinésárì ṣe ère wúrà kan, gíga rẹ̀ jẹ́ ọgọ́ta (60) ìgbọ̀nwọ́,* fífẹ̀ rẹ̀ sì jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ mẹ́fà.* Ó gbé e kalẹ̀ sí pẹ̀tẹ́lẹ̀ Dúrà ní ìpínlẹ̀* Bábílónì.