2 Kọ́ríńtì 11:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Mò ń jowú torí yín lọ́nà ti Ọlọ́run,* nítorí èmi fúnra mi ti fẹ́ yín sílẹ̀ de ọkọ kan, kí n lè mú yín wá fún Kristi bíi wúńdíá oníwà mímọ́.*+ Jémíìsì 1:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Ìjọsìn* tó mọ́, tí kò sì ní ẹ̀gbin lójú Ọlọ́run àti Baba wa nìyí: láti máa bójú tó àwọn ọmọ aláìlóbìí+ àti àwọn opó+ nínú ìpọ́njú wọn,+ ká sì máa pa ara wa mọ́ láìní àbààwọ́n nínú ayé.+ Jémíìsì 4:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ẹ̀yin alágbèrè,* ṣé ẹ ò mọ̀ pé bíbá ayé ṣọ̀rẹ́ ń sọni di ọ̀tá Ọlọ́run ni? Torí náà, ẹnikẹ́ni tó bá fẹ́ jẹ́ ọ̀rẹ́ ayé ń sọ ara rẹ̀ di ọ̀tá Ọlọ́run.+
2 Mò ń jowú torí yín lọ́nà ti Ọlọ́run,* nítorí èmi fúnra mi ti fẹ́ yín sílẹ̀ de ọkọ kan, kí n lè mú yín wá fún Kristi bíi wúńdíá oníwà mímọ́.*+
27 Ìjọsìn* tó mọ́, tí kò sì ní ẹ̀gbin lójú Ọlọ́run àti Baba wa nìyí: láti máa bójú tó àwọn ọmọ aláìlóbìí+ àti àwọn opó+ nínú ìpọ́njú wọn,+ ká sì máa pa ara wa mọ́ láìní àbààwọ́n nínú ayé.+
4 Ẹ̀yin alágbèrè,* ṣé ẹ ò mọ̀ pé bíbá ayé ṣọ̀rẹ́ ń sọni di ọ̀tá Ọlọ́run ni? Torí náà, ẹnikẹ́ni tó bá fẹ́ jẹ́ ọ̀rẹ́ ayé ń sọ ara rẹ̀ di ọ̀tá Ọlọ́run.+