Jóẹ́lì 3:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Ẹ ti dòjé bọ̀ ọ́, torí àkókò ìkórè ti tó. Ẹ sọ̀ kalẹ̀ wá tẹ èso àjàrà, torí ibi tí wọ́n ti ń fún wáìnì ti kún.+ Àwọn ẹkù ti kún àkúnwọ́sílẹ̀, torí ìwà búburú kún ọwọ́ àwọn orílẹ̀-èdè.
13 Ẹ ti dòjé bọ̀ ọ́, torí àkókò ìkórè ti tó. Ẹ sọ̀ kalẹ̀ wá tẹ èso àjàrà, torí ibi tí wọ́n ti ń fún wáìnì ti kún.+ Àwọn ẹkù ti kún àkúnwọ́sílẹ̀, torí ìwà búburú kún ọwọ́ àwọn orílẹ̀-èdè.