Jeremáyà 10:6, 7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Jèhófà, kò sí ẹni tó dà bí rẹ.+ O tóbi, orúkọ rẹ tóbi, ó sì kàmàmà. 7 Ta ni kò ní bẹ̀rù rẹ, ìwọ Ọba àwọn orílẹ̀-èdè,+ nítorí ó yẹ bẹ́ẹ̀;Láàárín gbogbo ọlọ́gbọ́n tó wà ní àwọn orílẹ̀-èdè àti ní gbogbo ìjọba wọn,Kò sí ẹnì kankan tó dà bí rẹ.+
6 Jèhófà, kò sí ẹni tó dà bí rẹ.+ O tóbi, orúkọ rẹ tóbi, ó sì kàmàmà. 7 Ta ni kò ní bẹ̀rù rẹ, ìwọ Ọba àwọn orílẹ̀-èdè,+ nítorí ó yẹ bẹ́ẹ̀;Láàárín gbogbo ọlọ́gbọ́n tó wà ní àwọn orílẹ̀-èdè àti ní gbogbo ìjọba wọn,Kò sí ẹnì kankan tó dà bí rẹ.+