Ìfihàn 8:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Áńgẹ́lì àkọ́kọ́ fun kàkàkí rẹ̀. Yìnyín àti iná dà pọ̀ mọ́ ẹ̀jẹ̀, a sì dà á sí ayé; + ìdá mẹ́ta ayé sì jóná àti ìdá mẹ́ta àwọn igi pẹ̀lú gbogbo ewéko tútù.+
7 Áńgẹ́lì àkọ́kọ́ fun kàkàkí rẹ̀. Yìnyín àti iná dà pọ̀ mọ́ ẹ̀jẹ̀, a sì dà á sí ayé; + ìdá mẹ́ta ayé sì jóná àti ìdá mẹ́ta àwọn igi pẹ̀lú gbogbo ewéko tútù.+