Ìfihàn 8:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Áńgẹ́lì kẹta fun kàkàkí rẹ̀. Ìràwọ̀ ńlá tó ń jó bíi fìtílà já bọ́ láti ọ̀run, ó já bọ́ sórí ìdá mẹ́ta àwọn odò àti sórí àwọn ìsun omi.*+
10 Áńgẹ́lì kẹta fun kàkàkí rẹ̀. Ìràwọ̀ ńlá tó ń jó bíi fìtílà já bọ́ láti ọ̀run, ó já bọ́ sórí ìdá mẹ́ta àwọn odò àti sórí àwọn ìsun omi.*+