Ìfihàn 1:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Àṣírí mímọ́ ti ìràwọ̀ méje tí o rí ní ọwọ́ ọ̀tún mi àti ti ọ̀pá fìtílà méje tí wọ́n fi wúrà ṣe náà nìyí: Ìràwọ̀ méje náà túmọ̀ sí àwọn áńgẹ́lì ìjọ méje, ọ̀pá fìtílà méje náà sì túmọ̀ sí ìjọ méje.+
20 Àṣírí mímọ́ ti ìràwọ̀ méje tí o rí ní ọwọ́ ọ̀tún mi àti ti ọ̀pá fìtílà méje tí wọ́n fi wúrà ṣe náà nìyí: Ìràwọ̀ méje náà túmọ̀ sí àwọn áńgẹ́lì ìjọ méje, ọ̀pá fìtílà méje náà sì túmọ̀ sí ìjọ méje.+