Ìfihàn 3:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 mo gbà ọ́ nímọ̀ràn pé kí o ra wúrà tí wọ́n fi iná yọ́ mọ́ lọ́dọ̀ mi, kí o lè di ọlọ́rọ̀, kí o ra aṣọ funfun kí o lè rí aṣọ wọ̀, kí ìtìjú má bàa bá ọ torí pé o wà ní ìhòòhò,+ kí o sì ra oògùn ojú láti fi pa ojú rẹ,+ kí o lè ríran.+
18 mo gbà ọ́ nímọ̀ràn pé kí o ra wúrà tí wọ́n fi iná yọ́ mọ́ lọ́dọ̀ mi, kí o lè di ọlọ́rọ̀, kí o ra aṣọ funfun kí o lè rí aṣọ wọ̀, kí ìtìjú má bàa bá ọ torí pé o wà ní ìhòòhò,+ kí o sì ra oògùn ojú láti fi pa ojú rẹ,+ kí o lè ríran.+