-
Ìsíkíẹ́lì 38:19Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
19 Ìtara àti ìbínú mi tó ń jó bí iná ni màá fi sọ̀rọ̀. Ní ọjọ́ yẹn, ìmìtìtì ilẹ̀ tó lágbára gan-an yóò ṣẹlẹ̀ ní ilẹ̀ Ísírẹ́lì.
-