Jémíìsì 4:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ẹ̀yin alágbèrè,* ṣé ẹ ò mọ̀ pé bíbá ayé ṣọ̀rẹ́ ń sọni di ọ̀tá Ọlọ́run ni? Torí náà, ẹnikẹ́ni tó bá fẹ́ jẹ́ ọ̀rẹ́ ayé ń sọ ara rẹ̀ di ọ̀tá Ọlọ́run.+ Ìfihàn 18:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 “Àwọn ọba ayé tó bá a ṣe ìṣekúṣe,* tí wọ́n sì jọ gbé ìgbé ayé gbẹdẹmukẹ láìnítìjú máa sunkún, ìbànújẹ́ nítorí rẹ̀ sì máa mú kí wọ́n lu ara wọn, tí wọ́n bá rí èéfín rẹ̀ nígbà tó ń jóná.
4 Ẹ̀yin alágbèrè,* ṣé ẹ ò mọ̀ pé bíbá ayé ṣọ̀rẹ́ ń sọni di ọ̀tá Ọlọ́run ni? Torí náà, ẹnikẹ́ni tó bá fẹ́ jẹ́ ọ̀rẹ́ ayé ń sọ ara rẹ̀ di ọ̀tá Ọlọ́run.+
9 “Àwọn ọba ayé tó bá a ṣe ìṣekúṣe,* tí wọ́n sì jọ gbé ìgbé ayé gbẹdẹmukẹ láìnítìjú máa sunkún, ìbànújẹ́ nítorí rẹ̀ sì máa mú kí wọ́n lu ara wọn, tí wọ́n bá rí èéfín rẹ̀ nígbà tó ń jóná.