Ìfihàn 17:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Áńgẹ́lì náà wá sọ fún mi pé: “Kí nìdí tó fi yà ọ́ lẹ́nu? Màá sọ ohun tó jẹ́ àdììtú nípa obìnrin náà+ fún ọ àti nípa ẹranko tó ń gbé e, èyí tó ní orí méje àti ìwo mẹ́wàá:+
7 Áńgẹ́lì náà wá sọ fún mi pé: “Kí nìdí tó fi yà ọ́ lẹ́nu? Màá sọ ohun tó jẹ́ àdììtú nípa obìnrin náà+ fún ọ àti nípa ẹranko tó ń gbé e, èyí tó ní orí méje àti ìwo mẹ́wàá:+