-
Ìfihàn 17:8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
8 Ẹranko tí ìwọ rí ti wà tẹ́lẹ̀, àmọ́ kò sí, síbẹ̀ ó máa tó jáde látinú ọ̀gbun àìnísàlẹ̀,+ ó sì máa lọ sí ìparun. Nígbà tí àwọn tó ń gbé ayé, ìyẹn àwọn tí a kò kọ orúkọ wọn sínú àkájọ ìwé ìyè+ látìgbà ìpìlẹ̀ ayé, bá sì rí bí ẹranko náà ṣe wà tẹ́lẹ̀, àmọ́ tí kò sí, síbẹ̀ tó tún máa wà, ó máa yà wọ́n lẹ́nu.
-