Ìfihàn 16:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Ìlú ńlá náà+ pín sí mẹ́ta, àwọn ìlú àwọn orílẹ̀-èdè sì ṣubú; a sì rántí Bábílónì Ńlá+ níwájú Ọlọ́run, ká lè fún un ní ife wáìnì tí ìbínú Ọlọ́run ń ru nínú rẹ̀.+
19 Ìlú ńlá náà+ pín sí mẹ́ta, àwọn ìlú àwọn orílẹ̀-èdè sì ṣubú; a sì rántí Bábílónì Ńlá+ níwájú Ọlọ́run, ká lè fún un ní ife wáìnì tí ìbínú Ọlọ́run ń ru nínú rẹ̀.+