Ìfihàn 6:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Sì wò ó! mo rí ẹṣin funfun kan,+ ẹni tó jókòó sórí rẹ̀ ní ọfà* kan; a sì fún un ní adé,+ ó jáde lọ, ó ń ṣẹ́gun, kó lè parí ìṣẹ́gun rẹ̀.+
2 Sì wò ó! mo rí ẹṣin funfun kan,+ ẹni tó jókòó sórí rẹ̀ ní ọfà* kan; a sì fún un ní adé,+ ó jáde lọ, ó ń ṣẹ́gun, kó lè parí ìṣẹ́gun rẹ̀.+