-
Ìfihàn 14:19, 20Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
19 Áńgẹ́lì náà ti dòjé rẹ̀ bọ ayé, ó kó àjàrà ayé jọ, ó sì jù ú síbi tí ó tóbi tí a ti ń fún wáìnì ti ìbínú Ọlọ́run.+ 20 A sì tẹ àjàrà náà ní òde ìlú náà, ẹ̀jẹ̀ sì tú jáde láti ibi tí a ti ń fún wáìnì náà, ó ga dé ìjánu àwọn ẹṣin, ó sì lọ jìnnà dé ẹgbẹ̀rún kan àti ọgọ́rùn-ún mẹ́fà (1,600) ìwọ̀n Sítédíọ̀mù.*
-