Ìfihàn 13:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 A gbà á láyè pé kó fún ère ẹranko náà ní èémí,* kí ère ẹranko náà lè sọ̀rọ̀, kó sì mú kí wọ́n pa gbogbo àwọn tó kọ̀ láti jọ́sìn ère ẹranko náà.
15 A gbà á láyè pé kó fún ère ẹranko náà ní èémí,* kí ère ẹranko náà lè sọ̀rọ̀, kó sì mú kí wọ́n pa gbogbo àwọn tó kọ̀ láti jọ́sìn ère ẹranko náà.