Ìfihàn 12:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Mo rí àmì míì ní ọ̀run. Wò ó! Dírágónì ńlá+ aláwọ̀ iná, ó ní orí méje àti ìwo mẹ́wàá, adé dáyádémà* méje sì wà ní àwọn orí rẹ̀;
3 Mo rí àmì míì ní ọ̀run. Wò ó! Dírágónì ńlá+ aláwọ̀ iná, ó ní orí méje àti ìwo mẹ́wàá, adé dáyádémà* méje sì wà ní àwọn orí rẹ̀;