Ìfihàn 9:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Wọ́n ní ẹni tó ń jọba lé wọn lórí, áńgẹ́lì ọ̀gbun àìnísàlẹ̀.+ Orúkọ rẹ̀ lédè Hébérù ni Ábádónì,* àmọ́ lédè Gíríìkì orúkọ rẹ̀ ni Ápólíónì.*
11 Wọ́n ní ẹni tó ń jọba lé wọn lórí, áńgẹ́lì ọ̀gbun àìnísàlẹ̀.+ Orúkọ rẹ̀ lédè Hébérù ni Ábádónì,* àmọ́ lédè Gíríìkì orúkọ rẹ̀ ni Ápólíónì.*