-
2 Àwọn Ọba 1:10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 Àmọ́ Èlíjà dá olórí àádọ́ta (50) ọmọ ogun náà lóhùn pé: “Ó dáa, tó bá jẹ́ pé èèyàn Ọlọ́run ni mí lóòótọ́, kí iná bọ́ láti ọ̀run,+ kó sì jó ìwọ àti àádọ́ta (50) ọkùnrin rẹ run.” Ni iná bá bọ́ láti ọ̀run, ó sì jó òun àti àádọ́ta (50) ọkùnrin rẹ̀ run.
-