Ìfihàn 13:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Ó* sì dúró jẹ́ẹ́ lórí iyanrìn òkun. Mo wá rí ẹranko kan+ tó ń jáde látinú òkun,+ ó ní ìwo mẹ́wàá àti orí méje, adé dáyádémà* mẹ́wàá sì wà lórí àwọn ìwo rẹ̀, àmọ́ àwọn orúkọ tó jẹ́ ọ̀rọ̀ òdì wà ní àwọn orí rẹ̀.
13 Ó* sì dúró jẹ́ẹ́ lórí iyanrìn òkun. Mo wá rí ẹranko kan+ tó ń jáde látinú òkun,+ ó ní ìwo mẹ́wàá àti orí méje, adé dáyádémà* mẹ́wàá sì wà lórí àwọn ìwo rẹ̀, àmọ́ àwọn orúkọ tó jẹ́ ọ̀rọ̀ òdì wà ní àwọn orí rẹ̀.