2 Pétérù 3:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Àmọ́ à ń retí ọ̀run tuntun àti ayé tuntun tó ṣèlérí,+ níbi tí òdodo á máa gbé.+